

Follow
34
1
Ogan Escanor Meliodas
Oyà A To Iwo Efòn Gbé Oyà Olókò Àra Obìnrin Ogun Obìnrin Ode Oya Òrírì Arójú Bá Oko Kú. Iru Èniyàn Wo Ni Oyà Yí N Se, Se? Ibi Oya Wà, Ló Gbiná Obìnrin Wóò Bi Eni Fó Igbá Oyà tí awon òtá rí Tí Won Torí Rè Da Igbá Nù Sì Igbó Héèpà Héè, Oya ò! Erù Re Nikan Ni Mo Nbà O Aféfé Ikú Obìnrin Ogun, Ti Ná Ibon Rè Ní À Ki Kún Oyà ò, Oyà Tótó Hun! Oyà, A P’Agbá, P’Àwo Mó Ni Kíákíá, Kíákíá, Wéré Wéré L’ Oyà Nse Ti È A Rìn Dengbere Bíi Fúlàní O Titi Tí Nfi Gbogbo Ará Rìn Bí Esin Héèpà, Oya Olómo Mesan, Ibá Re
More
Comment
Cancel
Send

Follow
2.9K
89
RAIMUNDA SALES OFICIAL
Olha só o que ela está fazendo #pelomenoseunao
More

Follow
230
1
RECEITAS MARA
#Receita #leitecondensado #arroz #arrozdoce #kwai
More